Isikiẹli 27:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní,

2. “Ìwọ ọmọ eniyan, kọ orin arò nípa ìlú Tire.

3. Sọ fún ìlú Tire tí ó wà ní etí òkun, tí ń bá gbogbo àwọn tí wọn ń gbé etí òkun ṣòwò. Sọ fún un pé OLUWA Ọlọrun ní:Tire, ìwọ tí ò ń sọ pé,o dára tóbẹ́ẹ̀, tí ẹwà rẹ kò kù síbìkan!

Isikiẹli 27