Isikiẹli 26:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, mo lòdì sí ọ, ìwọ Tire, n óo sì kó ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè wá gbógun tì ọ́, bíi ríru omi òkun.

Isikiẹli 26

Isikiẹli 26:1-8