Isikiẹli 26:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn erékùṣù yóo wárìrì ní ọjọ́ ìṣubú rẹ.Nítòótọ́, àwọn erékùṣù tí wọ́n wà ninu òkun yóo dààmú nítorí ìparun rẹ.”

Isikiẹli 26

Isikiẹli 26:8-19