Isikiẹli 25:17 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo gbẹ̀san lára wọn lọpọlọpọ; n óo fi ìrúnú fi ìyà ńlá jẹ wọ́n. Wọn óo wá mọ̀ nígbà tí mo bá gbẹ̀san lára wọn pé èmi ni OLUWA.”

Isikiẹli 25

Isikiẹli 25:16-17