Isikiẹli 25:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní, “Àwọn ará Filistia gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá wọn, wọn sì fi ìkórìíra àtayébáyé pa wọ́n run,

Isikiẹli 25

Isikiẹli 25:9-17