Isikiẹli 25:12 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní, “Nítorí àwọn ará Edomu gbẹ̀san lára àwọn ará Juda, wọ́n sì ṣẹ̀ nítorí ẹ̀san tí wọ́n gbà.

Isikiẹli 25

Isikiẹli 25:4-15