Isikiẹli 24:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo ti ṣe yìí gan-an ni ẹ̀yin náà gbọdọ̀ ṣe, ẹ kò gbọdọ̀ fi aṣọ bo ẹnu yín tabi kí ẹ máa jẹ oúnjẹ ọlọ́fọ̀.

Isikiẹli 24

Isikiẹli 24:14-27