Isikiẹli 24:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan bá bi mí pé, “Ṣé kò yẹ kí o sọ ohun tí nǹkan tí ó ń ṣẹlẹ̀ yìí túmọ̀ sí fún wa, tí o fi ń ṣe báyìí.”

Isikiẹli 24

Isikiẹli 24:9-20