Isikiẹli 24:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kó ọpọlọpọ igi jọ; ẹ ṣáná sí i. Ẹ se ẹran náà dáradára, ẹ da omi rẹ̀ nù, kí ẹ jẹ́ kí egungun rẹ̀ jóná.

Isikiẹli 24

Isikiẹli 24:2-15