Isikiẹli 23:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá gbogbo àwọn eniyan pataki pataki Asiria ṣe àgbèrè, ó sì fi oriṣa gbogbo àwọn tí ó ń ṣẹ́jú sí ba ara rẹ̀ jẹ́.

Isikiẹli 23

Isikiẹli 23:1-11