Isikiẹli 23:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jókòó lórí àga ọlọ́lá. Ẹ tẹ́ tabili siwaju; ẹ wá gbé turari ati òróró mi lé e lórí.

Isikiẹli 23

Isikiẹli 23:39-49