Isikiẹli 23:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí nìkan kọ́ ni wọ́n ṣe sí mi, wọ́n sọ ibi mímọ́ mi di eléèérí, wọ́n sì ba àwọn ọjọ́ ìsinmi mi jẹ́.

Isikiẹli 23

Isikiẹli 23:33-42