Isikiẹli 23:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun ní, “Nítorí pé o ti gbàgbé mi, o sì ti kọ̀ mí sílẹ̀, o óo jìyà ìṣekúṣe ati àgbèrè rẹ.”

Isikiẹli 23

Isikiẹli 23:27-44