Isikiẹli 23:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyà óo jẹ ọ́ lọpọlọpọ,ìbànújẹ́ óo sì dé bá ọ.N óo mú ìpayà ati ìsọdahoro bá ọ,bí mo ṣe mú un bá Samaria, ẹ̀gbọ́n rẹ.

Isikiẹli 23

Isikiẹli 23:31-42