Isikiẹli 23:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Oholiba, àbúrò rẹ̀ rí èyí, sibẹsibẹ, ojú ṣíṣẹ́ sí ọkunrin ati àgbèrè tirẹ̀ burú ju ti ẹ̀gbọ́n rẹ̀ lọ.

Isikiẹli 23

Isikiẹli 23:9-15