Isikiẹli 22:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ kò náání baba ati ìyá wọn ninu rẹ; wọ́n sì ń ni àwọn àjèjì ninu rẹ lára; wọ́n sì ń fìyà jẹ àwọn aláìníbaba ati opó.

Isikiẹli 22

Isikiẹli 22:5-10