Isikiẹli 22:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n súnmọ́ ọ ati àwọn tí wọ́n jìnnà sí ọ yóo máa fi ọ́ ṣe yẹ̀yẹ́, ìwọ tí o kò níyì, tí o kún fún ìdàrúdàpọ̀.

Isikiẹli 22

Isikiẹli 22:1-6