Isikiẹli 22:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Sọ fún un pé èmi OLUWA Ọlọrun ní, ìwọ ìlú tí wọ́n ti ń paniyan ní ìpakúpa kí àkókò ìjìyà rẹ̀ lè tètè dé, ìlú tí ń fi oriṣa ba ara rẹ̀ jẹ́!

Isikiẹli 22

Isikiẹli 22:1-5