Isikiẹli 22:24 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé ilẹ̀ tí kò mọ́ ni ilẹ̀ wọn, ilẹ̀ tí òjò kò rọ̀ sí lákòókò ibinu èmi OLUWA.

Isikiẹli 22

Isikiẹli 22:19-31