Isikiẹli 22:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun ní níwọ̀n ìgbà tí gbogbo yín ti di ìdàrọ́, n óo ko yín jọ sí ààrin Jerusalẹmu.

Isikiẹli 22

Isikiẹli 22:13-26