Isikiẹli 21:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, máa mí ìmí ẹ̀dùn, bí ẹni tí ọkàn rẹ̀ ti dàrú, tí ó sì ń kẹ́dùn níwájú wọn.

Isikiẹli 21

Isikiẹli 21:1-8