Isikiẹli 21:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìparun! Ìparun! N óo pa ìlú yìí run ni; ṣugbọn n kò ní tíì pa á run, títí ẹni tí ó ni í yóo fi dé, tí n óo sì fi lé e lọ́wọ́.

Isikiẹli 21

Isikiẹli 21:26-32