Isikiẹli 21:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, kọjú sí Jerusalẹmu kí o sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí ibi mímọ́ Israẹli. Sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ilẹ̀ Israẹli.

Isikiẹli 21

Isikiẹli 21:1-10