Isikiẹli 21:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àyà wọn lè já, kí ọpọlọpọ lè kú ní ẹnubodè wọn. Mo ti fi idà tí ń dán lélẹ̀ fún pípa eniyan, ó ń kọ mànà bíi mànàmáná, a sì ti fi epo pa á.

Isikiẹli 21

Isikiẹli 21:11-24