Isikiẹli 20:46 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, kọjú sí ìhà gúsù, fi iwaasu bá ìhà ibẹ̀ wí, kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa àwọn ilẹ̀ igbó Nẹgẹbu.

Isikiẹli 20

Isikiẹli 20:39-49