Isikiẹli 20:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA nígbà tí mo bá ko yín dé ilẹ̀ Israẹli, ilẹ̀ tí mo búra láti fún àwọn baba ńlá yín.

Isikiẹli 20

Isikiẹli 20:34-43