Isikiẹli 20:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣé o óo ṣe ìdájọ́ wọn? Ìwọ ọmọ eniyan, ṣé o óo ṣe ìdájọ́ wọn? Jẹ́ kí wọ́n mọ àwọn nǹkan ìríra tí àwọn baba wọn ṣe.

Isikiẹli 20

Isikiẹli 20:1-5