Isikiẹli 20:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo ṣe dájọ́ àwọn baba ńlá yín ní aṣálẹ̀ ilẹ̀ Ijipti ni n óo dájọ́ yín. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Isikiẹli 20

Isikiẹli 20:34-42