Isikiẹli 20:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bi wọ́n léèrè pé irú ibi pẹpẹ ìrúbọ wo ni ẹ tilẹ̀ ń lọ ríì? Nítorí náà ni wọ́n ṣe ń pe ibẹ̀ ní Bama títí di òní.

Isikiẹli 20

Isikiẹli 20:21-30