Isikiẹli 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Aláfojúdi ati olóríkunkun ẹ̀dá ni wọ́n. Mò ń rán ọ sí wọn kí o lè sọ ohun tí èmi OLUWA Ọlọrun wí fún wọn.

Isikiẹli 2

Isikiẹli 2:1-10