Isikiẹli 19:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn a fa àjàrà náà tu pẹlu ibinu,a sì jù ú sílẹ̀.Afẹ́fẹ́ ìlà oòrùn mú kí ó gbẹ,gbogbo èso rẹ̀ sì rẹ̀ dànù.Igi rẹ̀ tí ó lágbára gbẹ, iná sì jó o.

Isikiẹli 19

Isikiẹli 19:3-14