Isikiẹli 19:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyá rẹ dàbí àjàrà inú ọgbàtí a gbìn sí ẹ̀gbẹ́ odò;ó rúwé, ó yọ ẹ̀ka,nítorí ó rí omi lọpọlọpọ.

Isikiẹli 19

Isikiẹli 19:8-12