Isikiẹli 18:32 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò ní inú dídùn sí ikú ẹnikẹ́ni, nítorí náà, ẹ yipada kí ẹ lè yè. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Isikiẹli 18

Isikiẹli 18:25-32