Isikiẹli 18:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹsibẹ àwọn ọmọ Israẹli ń wí pé, ‘Ọ̀nà OLUWA kò tọ́.’ Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ṣé ọ̀nà mi ni kò tọ́, àbí tiyín?

Isikiẹli 18

Isikiẹli 18:23-31