Isikiẹli 18:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí eniyan burúkú bá sì yipada kúrò ninu ìwà ibi rẹ̀, tí ó sì ń ṣe rere, yóo gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là.

Isikiẹli 18

Isikiẹli 18:23-32