Isikiẹli 18:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kí ni ẹ rí tí ẹ fi ń pa irú òwe yìí nípa ilẹ̀ Israẹli, tí ẹ̀ ń sọ pé,‘Àwọn baba ni wọ́n jẹ èso àjàrà tí ó kan,ni eyín fi kan àwọn ọmọ?’

Isikiẹli 18

Isikiẹli 18:1-8