Isikiẹli 18:12 BIBELI MIMỌ (BM)

tí ń ni talaka ati aláìní lára, tí ń fi ipá jalè, tí kì í dá ohun tí onígbèsè rẹ̀ bá fi ṣe ìdúró pada fún un, tí ń bọ oriṣa, tí ń ṣe ohun ìríra,

Isikiẹli 18

Isikiẹli 18:3-14