Isikiẹli 17:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó mú ninu èso ilẹ̀ náà, ó gbìn ín sí ilẹ̀ kan tí ó lọ́ràá, ní ẹ̀bá odò. Ó gbìn ín bí wọn tíí gbin igi wilo.

Isikiẹli 17

Isikiẹli 17:1-9