Isikiẹli 17:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ní sá àsálà, nítorí pé kò náání ìbúra ó sì da majẹmu, ati pé ó ti tọwọ́ bọ ìwé, sibẹsibẹ, ó tún ṣe gbogbo nǹkan tí ó ṣe.”

Isikiẹli 17

Isikiẹli 17:13-24