Isikiẹli 17:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“Èmi OLUWA fi ara mi búra pé, ní ilẹ̀ Babiloni, ní ilẹ̀ ọba tí ó fi í sórí oyè ọba tí kò náání, tí ó sì da majẹmu rẹ̀, níbẹ̀ ni yóo kú sí.

Isikiẹli 17

Isikiẹli 17:7-19