Isikiẹli 16:7 BIBELI MIMỌ (BM)

kí o sì dàgbà bí irúgbìn oko. Ni o bá dàgbà, o ga, o sì di wundia, ọyàn rẹ yọ, irun rẹ sì hù, sibẹ o wà ní ìhòòhò.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:4-17