Isikiẹli 16:50 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbéraga, wọ́n sì ṣe nǹkan ìríra níwájú mi. Nítorí náà, nígbà tí mo rí ohun tí wọn ń ṣe, mo pa wọ́n run.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:48-59