Isikiẹli 16:48 BIBELI MIMỌ (BM)

“Èmi OLUWA Ọlọrun fi ara mi búra pé, Sodomu arabinrin rẹ ati àwọn ọmọ rẹ̀ obinrin kò tíì ṣe tó ohun tí ìwọ ati àwọn ọmọbinrin rẹ ṣe.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:46-57