Isikiẹli 16:46 BIBELI MIMỌ (BM)

“Samaria ni ẹ̀gbọ́n rẹ, òun ati àwọn ọmọ rẹ̀ ń gbé ìhà àríwá. Sodomu ni àbúrò rẹ, òun ati àwọn ọmọ rẹ̀ ń gbé ìhà gúsù.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:43-48