Isikiẹli 16:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni n óo ṣe tẹ́ ibinu mi lọ́rùn lára rẹ, n kò sì ní jowú nítorí rẹ mọ́. Ara mi yóo rọlẹ̀, inú kò sì ní bí mi mọ́.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:40-48