Isikiẹli 16:28 BIBELI MIMỌ (BM)

“O bá àwọn ará Asiria ṣe àgbèrè ẹ̀sìn pẹlu, nítorí pé o kò ní ìtẹ́lọ́rùn sibẹ, lẹ́yìn gbogbo àgbèrè tí o ṣe pẹlu wọn, o kò ní ìtẹ́lọ́rùn.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:22-35