Isikiẹli 16:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ò ń ṣe àgbèrè ati gbogbo nǹkan ìríra rẹ, o kò ranti ìgbà èwe rẹ, nígbà tí o wà ní ìhòòhò goloto, tí ò ń ta ẹsẹ̀ ninu ẹ̀jẹ̀!”

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:12-23