Isikiẹli 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá wọ̀ ọ́ ní aṣọ tí wọ́n ṣe ọnà sí lára, mo wọ̀ ọ́ ní bàtà aláwọ. Mo wọ̀ ọ́ ní aṣọ funfun, mo sì dá ẹ̀wù siliki fún ọ.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:8-11