Isikiẹli 15:7 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dójú lé wọn, bí wọn tilẹ̀ yọ jáde ninu iná, sibẹsibẹ iná ni yóo jó wọn. Nígbà tí mo bá dójú lé wọn, ẹ óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA.

Isikiẹli 15

Isikiẹli 15:1-8