Isikiẹli 14:8 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dójú lé olúwarẹ̀, n óo fi ṣe ẹni àríkọ́gbọ́n ati àmúpòwe. N óo pa á run láàrin àwọn eniyan mi; ẹ óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA.

Isikiẹli 14

Isikiẹli 14:1-12